Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Ijọba Naijiria ti bẹrẹ igbẹjọ

lori awọn eeyan to n poogun oloro ati kẹmika lọna aitọ ti ijọba ṣawari wọn loṣu karun-un

BBC News ṣabẹwo si ibudo ti wọn ti ṣawari awọn kemika naa ti igbẹjọ ti waye lọjọru

Awọn ohun ti a ṣawari nibẹ wa loju opo bbcnews.com/Yoruba

___________________________________________________

Mo ti ṣetan lati ṣe alagbatọ fawọn ọmọ mẹtẹẹta John Olaleye,

Ẹlẹyinju-aanu, Dokita Kunle Adegbite olukọ ile ẹkọ Esinele to padanu ẹmi rẹ si ahamọ ajinigbe

Adegbite to n dije sile aṣoju-ṣofin lẹgbẹ oṣelu NDC fun ẹkun Ogbomoso North ati South

Kede pe nipasẹ ajọ alaanu Twindad Foundation loun yoo fi ṣe alagbatọ awọn ọmọ mẹta ọhun

Ẹkunrẹrẹ wa loju opo wa

___________________________________________________

Irọ patapata gbu u ni gbogbo iroyin tawọn eeyan kan n gbe lori iku Abacha

Sẹnetọ Shehu Sani ti ipinlẹ Kaduna ni ọrọ ẹnu lasan ni ọrọ ti igbakeji olori oṣiṣẹ DSS tẹlẹ ri, Dennis Amachree gbe jade

Lori ohun to ṣokunfa iku Abacha lodi si ohun tawọn eeyan mọ tẹlẹ

Ki ni Amachree sọ nipa iku Abacha?