You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Aarẹ Tinubu ti buwọlu afikun ẹkun ileeṣẹ ologun lati mẹjọ di mejila
Lojuna ati koju ipenija igbeṣumọmi ati ikọlu awọn agbebọn
Tinubu tun kede gbigba awọn ọmọ ogun ẹgbẹrun mejidinlọgbọn
Amọ awọn onimọ nipa eto aabo ti fi erongba wọn han lori igbesẹ naa
Ki ni wọn sọ?
Ka a loju opo wa
___________________________________________________
Ninu iroyin mii
Oloye Sunday Igboho ti ṣe ifilọlẹ ikọ eleto àabò Iru Ẹkun ni ipinlẹ Kwara
Lojuna ati mu eto aabo gbopọn lẹkun guusu Kwara
Igboho sọ pe ọdaran ni wọn maa ẹnikẹni ti awọn ba ba ibọn lọwọ rẹ ninu Igbo lai se ọdẹ tabi vigilante kun
To si ṣalaye bi eeyan ṣe le darapọ mọ ẹgbẹ naa
Ẹkunrẹrẹ wa ni bbc.com/Yoruba
___________________________________________________
Ijọba ipinlẹ Osun ti fofin de ẹgbẹ NURTW ati roodu
Lati dawọ jija tikẹẹti fawọn ọlọkọ ati ọlọkada ni garaaji duro fun igba kan na
Atẹjade ti Kọmiṣanna feto iroyin, Kolapo Alimi fi lede ṣalaye pe
Igbesẹ naa n waye lẹyin ipade pẹlu awọn ẹṣọ aabo lati dena ikọlu ojoojumọ to n waye ni ipinlẹ naa